Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé Ní Héb., “àti àwọn Késílì wọn,” ó ṣeé ṣe kó jẹ́ Óríónì àtàwọn àgbájọ ìràwọ̀ tó yí i ká ló ń tọ́ka sí.