Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé Nínú ẹsẹ yìí àti àwọn tó tẹ̀ lé e, “Náílì” ń tọ́ka sí odò yẹn gangan àti àwọn odò tó ṣàn jáde látinú rẹ̀.