Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé “Ọmọ èèyàn”; èyí ni ìgbà àkọ́kọ́ nínú ìgbà 93 tí ọ̀rọ̀ yìí fara hàn nínú ìwé Ìsíkíẹ́lì.