Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé Ó ṣeé ṣe kí àwọn òrìṣà méjèèjì yìí máa tọ́ka sí pílánẹ́ẹ̀tì Sátọ̀n tí wọ́n ń sìn bí ọlọ́run.