Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Ìwọ̀n àìríṣẹ́ṣe ni ìpín ọrún àròpọ̀ àwọn tí wọ́n tóótun láti ṣiṣẹ́ ṣùgbọ́n tí wọn kò ríṣẹ́ ṣe.