Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a A kò ní àyè tó láti kọ gbogbo àkọsílẹ̀ onítàn yìí jáde. Bí ó ti wù kí ó rí, ìtòlẹ́sẹẹsẹ àwọn ìwé ìtọ́kasí wà ní kíkún tí àwọn tó ṣe ìwé yìí jáde lè pèsè bí a bá béèrè fún un. O tún lè mọ púpọ̀ sí i nípa wíwo fídíò Jehovah’s Witnesses Stand Firm Against Nazi Assault.