Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé b Oyin kì í ṣe oúnjẹ tó dáa fáwọn ọmọdé nítorí pé ó lè mú kí wọ́n ní àrùn tó máa ń sọ ara di ahẹrẹpẹ.