Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Ẹ̀kọ́ Mẹ́talọ́kan tí kò bá Ìwé Mímọ́ mu, èyí tó fi Jésù pe Ọlọ́run, ló fà á tí wọ́n fi ń pe Màríà ní ìyá Ọlọ́run.