Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Lára irú àpẹẹrẹ bẹ́ẹ̀ ni báwọn àlùfáà ṣe máa ń gba owó ìdáríjì ẹ̀ṣẹ̀, fífi ìyà jẹ ẹni tó bá ta ko ẹ̀kọ́ ṣọ́ọ̀ṣì, àti báwọn àlùfáà ṣe ń dáná sun Bíbélì káwọn ọmọ ìjọ má bàa ní in lọ́wọ́.—Wo ìwé ìròyìn wa kejì, ìyẹn Ilé Ìṣọ́ November 15, 2002, ojú ìwé 27.