Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Bí o kò bá ní Bíbélì, o lè gba ọ̀kan lọ́wọ́ àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà. Bó o bá sì mọ bí wọ́n ṣe ń lo Íńtánẹ́ẹ̀tì, o lè ka Bíbélì lórí ìkànnì wa ní oríṣiríṣi èdè, ìyẹn, www.watchtower.org. (Ní báyìí, kò tíì sí Bíbélì èdè Yorùbá níbẹ̀). Bákan náà, àwọn ìwé tá a fi ń kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì wà lórí Ìkànnì wa, ní èdè tó lé ní irinwó dín ogún [380].