Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Bí ìbànújẹ́ bá kọ̀ tí kò lọ kúrò lọ́kàn àwọn ọ̀dọ́ kan, wọ́n máa ń fẹ́ pa ara wọn. Bí irú èrò yìí bá ti wá sí ẹ lọ́kàn, tètè fọ̀rọ̀ náà lọ àgbàlagbà kan tó o fọkàn tán.—Wo Jí! July–September 2008, ojú ìwé 16 sí 18.