Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ìwé ìròyìn Jí! kò sọ pé ìkànnì orí Íńtánẹ́ẹ̀tì kan ló dára tàbí pé ọkàn kò dára. Àwọn Kristẹni gbọ́dọ̀ rí i pé, ọ̀nà tí wọ́n gbà ń lo Íńtánẹ́ẹ̀tì kò ta ko àwọn ìlànà Bíbélì.—1 Tímótì 1:5, 19.