Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c Àwọn ìgbà míì wà tí kò bọ́gbọ́n mu pé kéèyàn fi ọ̀rọ̀ pa mọ́. Bí àpẹẹrẹ, bí ọ̀rẹ́ rẹ bá dá ẹ̀ṣẹ̀ ńlá kan, tó bá ń gbèrò láti pa ara rẹ̀, tàbí tó bá ń ṣe àwọn nǹkan tó lè ṣe ìpalára fún un. Tó o bá fẹ́ àlàyé sí i, wo Jí! January–March 2009, ojú ìwé 19 sí 21, àti July–September 2008, ojú ìwé 16 sí 19.