Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Fún ìsọfúnni síwájú sí i nípa ìgbéyàwó, wo Ilé Ìṣọ́ February 1, 2011, ìyẹn ìwé ìròyìn tó ṣìkejì ìwé ìròyìn Jí!
KÍ LÈRÒ RẸ?
● Ojú wo ni Ọlọ́run fi ń wo ìkọ̀sílẹ̀?—Málákì 2:14-16.
● Báwo ló ṣe yẹ kí ọkọ máa hùwà sí ìyàwó rẹ̀?—Éfésù 5:23, 28.
● Ọgbọ́n ta ló máa ń jẹ́ kí ìgbéyàwó wà pẹ́ títí?—Sáàmù 1:2, 3.