Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé b Tó o bá fẹ́ mọ ìdí tí Ọlọ́run fi fàyè gba ìyà fúngbà díẹ̀ àti bó ṣe máa fòpin sí i, lọ wo orí 8 àti 11 nínú ìwé Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà la ṣe é.