Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Àwọn ọmọléèwé gíga lórílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà sábà máa ń nírú ìṣòro yìí. Ìwé ìròyìn The Wall Street Journal sọ pé, gbèsè tó máa ń wà lọ́rùn àwọn ọmọ tó yáwó lọ sí iléèwé máa ń tó $33,000 [nǹkan bíi mílíọ̀nù mẹ́fà ààbọ̀ náírà] nígbà tí wọ́n bá fi máa jáde nílé ìwé.