Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a B.C.E. túmọ̀ sí “ṣáájú Sànmánì Tiwa,” èyí tí ó tọ̀nà ju B.C. (“ṣáájú Kristi”). C.E. dúró fún “Sànmánì Tiwa,” tí a sábà máa ń pè ní A.D., fún anno Domini, tí ó túmọ̀ sí “ní ọdún Oluwa wa.”