Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Àwọn ọ̀mọ̀wé akẹ́kọ̀ọ́jinlẹ̀ kan gbà gbọ́ pé àwọn nǹkan bí àtíbàbà tàbí ahéré, tí kì í pẹ́, tó sì rọrùn láti kọ́, ló wọ́pọ̀ ju ilé gogoro olókùúta lọ. (Aísáyà 1:8) Wíwà tí ilé gogoro wà níbẹ̀ fi hàn pé ọlọ́gbà àjàrà náà sa ipá àrà ọ̀tọ̀ lórí “ọgbà àjàrà” rẹ̀.