Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Inú ọ̀rọ̀ náà ma·shiʹach lédè Hébérù ni “Mèsáyà” tó túmọ̀ sí “Ẹni Àmì Òróró” ti wá. Ọ̀rọ̀ tó bá a dọ́gba lédè Gíríìkì ni Khri·stosʹ, tàbí “Kristi.”—Mátíù 2:4, àlàyé ìsàlẹ̀ ìwé, NW.