Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Gẹ́gẹ́ bíi Josephus, òpìtàn ọ̀rúndún kìíní ṣe wí, lọ́dún 70 Sànmánì Tiwa, ìyàn mú tó bẹ́ẹ̀ gẹ́ẹ́ ní Jerúsálẹ́mù, táwọn èèyàn fi ń jẹ irú awọ bíi awọ bàtà, koríko, àti èérún koríko. Ìròyìn kan sọ pé ìyá kan sun ọmọ rẹ̀ jẹ.