Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c Lọ́nà mìíràn, ó lè jẹ́ àwọn ará Táṣíṣì ni “ọmọbìnrin Táṣíṣì” tọ́ka sí. Ìwé kan sọ pé: “Gẹ́gẹ́ bí Odò Náílì ṣe lè ṣàn káàkiri fàlàlà làwọn ará Táṣíṣì ṣe lè rìnrìn àjò kiri, kí wọ́n sì ṣòwò fàlàlà wàyí.” Síbẹ̀ náà, ohun tó máa tẹ̀yìn ìṣubú Tírè yọ ló ń tẹnu mọ́.