Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Nínú Hébérù ìjímìjí, ọ̀rọ̀ tó dún bára jọ gẹ́gẹ́ bí àkọ́sórí àwọn ọmọ jẹ́lé-ó-sinmi ni ọ̀rọ̀ inú Aísáyà 28:10. Nípa bẹ́ẹ̀, ńṣe ni ọ̀rọ̀ Aísáyà dún létí àwọn aṣáájú ìsìn wọ̀nyẹn bí àsọtúnsọ tó jọ atata-n-toto tí ìkókó máa ń sọ.