Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Iye rẹ̀ ju mílíọ̀nù mẹ́sàn-án ààbọ̀ owó dọ́là (ti ilẹ̀ Amẹ́ríkà) lọ bí a bá gbé e karí ìdiwọ̀n ti lọ́ọ́lọ́ọ́.