Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Wọ́n ti ṣírò rẹ̀ pé “ìwọ̀n àwọn agbami òkun jẹ́ nǹkan bí 1.35 quintillion (1.35 x 1018) tọ́ọ̀nù lórí ìwọ̀n, ìyẹn ni pé, ká sọ pé a pín ìwọ̀n gbogbo Ilẹ̀ Ayé sí nǹkan bí ọ̀nà egbèjìlélógún [4,400], agbami òkun yóò kó ìdá kan rẹ̀.”—Encarta 97 Encyclopedia.