Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c Ìwé The Expositor’s Bible Commentary sọ pé: “Nínú ètò káràkátà inú ọjà ní ìhà Ìlà Oòrùn Ayé, bí wọ́n bá fẹ́ wọn ẹran tàbí èso lórí òṣùwọ̀n, wọn kì í ka ẹ̀kán omi kíún tó bá wà nínú korobá òṣùwọ̀n tàbí ekuru díẹ̀ tó bá wà lórí òṣùwọ̀n sí nǹkan kan.”