Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Èrò tó wọ́pọ̀ láàárín àwọn ará Ìwọ̀ Oòrùn ayé nípa mìlẹ́níọ̀mù tuntun la ń tọ́ka sí níbí o. Táa bá ní ká sọ bó ṣe jẹ́ gan-an, January 1, 2001 ni mìlẹ́níọ̀mù tuntun máa tó bẹ̀rẹ̀.