Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Bíbélì sábà máa ń fi òtítọ́ wé ìmọ́lẹ̀. Onísáàmù kan kọ ọ́ lórin pé: “Rán ìmọ́lẹ̀ rẹ àti òtítọ́ rẹ jáde.” (Sáàmù 43:3) Jèhófà ń jẹ́ kí ìmọ́lẹ̀ òtítọ́ tàn sórí àwọn tó bá fẹ́ gba ẹ̀kọ́ látọ̀dọ̀ ẹ̀.—2 Kọ́ríńtì 4:6; 1 Jòhánù 1:5.