Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ìṣípayá 5:11 sọ nípa àwọn áńgẹ́lì tó jẹ́ olóòótọ́ pé: “Iye wọn sì jẹ́ ẹgbẹẹgbàárùn-ún lọ́nà ẹgbẹẹgbàárùn-ún.” Nípa bẹ́ẹ̀, Bíbélì fi hàn pé ọgọ́rọ̀ọ̀rún mílíọ̀nù áńgẹ́lì ni Ọlọ́run dá.