Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé b Ìgbà tí òbí bá ní kí ọmọ ṣe ohun tó lòdì sí òfin Ọlọ́run nìkan ni kò yẹ kí ọmọ gbọ́ràn sí i lẹ́nu.—Ìṣe 5:29.