Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Àwọn ẹ̀mí búburú pàápàá lè fipá ṣègbọràn. Nígbà tí Jésù pàṣẹ fáwọn ẹ̀mí èṣù pé kí wọ́n jáde kúrò lára àwọn kan tó lẹ́mìí èṣù, kò sí ohun táwọn ẹ̀mí èṣù náà lè ṣe ju pé kí wọ́n tẹrí ba kí wọ́n sì ṣègbọràn, bó tilẹ̀ jẹ́ pé kò tinú wọn wá.—Máàkù 1:27; 5:7-13.