Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c Mátíù 23:4 lo ọ̀rọ̀ yìí láti ṣàpèjúwe “àwọn ẹrù wíwúwo,” ìyẹn àwọn òfin jáǹtìrẹrẹ àtàwọn àṣà àtọwọ́dọ́wọ́ táwọn akọ̀wé àtàwọn Farisí gbé ka àwọn èèyàn lórí. Ọ̀rọ̀ kan náà yìí la tú sí “aninilára” nínú Ìṣe 20:29, 30, ó sì ń tọ́ka sí àwọn apẹ̀yìndà tí wọ́n ń ni àwọn èèyàn lára, tí wọ́n ń “sọ àwọn ohun àyídáyidà,” tí wọ́n sì ń wọ́nà láti ṣi àwọn ẹlòmíì lọ́nà.