Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé b Wo Orí 13 ìwé yìí níbi tá a ti jíròrò àwọn ayẹyẹ àtàwọn àṣà ìbílẹ̀ táwa Kristẹni tòótọ́ kì í lọ́wọ́ sí.