Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Lójú ohun tí Bíbélì sọ àti ohun tí ìtàn jẹ́ ká mọ̀, oṣù Étánímù ti àwọn Júù lọ́dún 2 ṣáájú Sànmánì Kristẹni ni wọ́n bí Jésù, oṣù Étánímù yìí sì wà láàárín oṣù September àti October lórí Kàlẹ́ńdà tá à ń lò báyìí.—Wo Insight on the Scriptures, Apá Kejì, ojú ìwé 56 àti 57, táwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ṣe.