Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
e Ìwádìí tún ti fi hàn pé ọdún àjíǹde ní nǹkan ṣe pẹ̀lú bíbọ abo òòṣà ìbímọlémọ àwọn ará Fòníṣíà tí wọ́n ń pè ní Ásítátè torí ẹyin àti ehoro làwọn àmì rẹ̀. Nínú oríṣiríṣi ère Ásítátè, wọ́n máa ń yà á bí ẹni tó ní ẹ̀yà ìbálòpọ̀ tó ṣàrà ọ̀tọ̀, tàbí kí wọ́n ya ehoro sẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀ kó sì tún mú ẹyin dání.