Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c Ọ̀tọ̀ ni síkéèlì tí wọ́n fi ń wọn ọjà kí wọ́n tó rà á, ọ̀tọ̀ sì lèyí tí wọ́n fi ń wọ̀n ọ́n tí wọ́n bá fẹ́ tà á, nítorí àtijèrè àbòsí. Wọ́n tún lè lo òṣùwọ̀n tó gùn lápá kan tàbí èyí tí apá ẹ̀ kan wúwo ju ìkejì lọ láti fi rẹ́ àwọn oníbàárà wọn jẹ.