Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Ọgbọ́n táwọn ìdílé kan dá sí i, kí ẹnikẹ́ni má bàa lo kọ̀ǹpútà tí wọ́n ní sílé láti wòwòkuwò ni pé wọ́n gbé e síbi tójú ti lè tó o. Láfikún sí ìyẹn, àwọn ìdílé kan ra ohun tó máa ń dènà àwòrán búburú sínú kọ̀ǹpútà wọn. Àmọ́, ó níbi tí wọ́n ń ṣiṣẹ́ mọ o.