Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c Bó o bá ń fẹ́ ìdámọ̀ràn tó lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ nípa bó o ṣe lè ṣẹ́pá ìṣòro fífọwọ́ pa ẹ̀yà ìbímọ rẹ, wo àpilẹ̀kọ náà, “Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé . . . Báwo Ni Mo Ṣe Lè Jáwọ́ Nínú Àṣà Búburú Yìí?” nínú Jí! January–March 2007, àti ojú ìwé 205 sí 211 nínú ìwé Awọn Ìbéèrè Tí Awọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè Awọn Ìdáhùn Tí Ó Gbéṣẹ́, Apá Kìíní.