Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Bó bá jẹ́ pé ẹnì kan ló ń yọ ẹ́ lẹ́nu níléèwé, wo àwọn àbá tó lè wúlò fún ẹ ní Orí 14 nínú ìwé yìí. Àmọ́, bó bá jẹ́ pé ọ̀rẹ́ ẹ ló ṣe ohun tó bí ẹ nínú, ìsọfúnni tó wà ní Orí 10 lè ràn ẹ́ lọ́wọ́.