Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c Bójú bá ń tì ẹ́ láti sọ bó ṣe ń ṣe ẹ́ fẹ́nì kan lójúkojú, gbìyànjú láti kọ lẹ́tà tàbí kó o bá onítọ̀hún sọ̀rọ̀ lórí fóònù. Ohun tó sábà máa ń ran èèyàn lọ́wọ́ jù lọ láti borí ìdààmú ọkàn ni pé kó sọ bó ṣe ń ṣe é fún ẹlòmíì.