Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé f Wọ́n ṣètò yìí fún ìgbà díẹ̀ kó lè ṣeé ṣe fáwọn àlejò tó wá sí Jerúsálẹ́mù láti kẹ́kọ̀ọ́ sí i. Ńṣe ni wọ́n fi tinútinú yọ̀ǹda àwọn nǹkan tí wọ́n ní, kì í ṣe pé ẹnikẹ́ni fipá mú wọn.—Ìṣe 5:1-4.