Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé h Lọ́pọ̀ ọdún lẹ́yìn náà, Pọ́ọ̀lù kọ lẹ́tà sáwọn ará Gálátíà. Nínú lẹ́tà yẹn, Pọ́ọ̀lù sọ pé: “Àìsàn tó ṣe mí ló jẹ́ kí n kọ́kọ́ láǹfààní láti kéde ìhìn rere fún yín.”—Gál. 4:13.