Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé e Ọjọ́ márùn-ún ni wọ́n lò lọ́nà kí wọ́n tó dé Tíróásì láti ìlú Fílípì. Ó lè jẹ́ ẹ̀fúùfù ló ṣèdíwọ́ fún wọn, torí pé ọjọ́ méjì péré ni wọ́n lò lọ́nà nígbà tí wọ́n kọ́kọ́ lọ sí ìlú yìí.—Ìṣe 16:11.