Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c Ó ní láti jẹ́ pé àṣìṣe látọwọ́ àwọn adàwékọ ló fà á tí orúkọ Jèhóákímù fi wà nínú Jeremáyà 27:1, torí pé ọ̀rọ̀ Sedekáyà ni ẹsẹ kẹta àti ìkejìlá ń sọ.