Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Má rò pé ọ̀ranyàn ni kó o sunkún torí bó ṣe dùn ẹ́ tó. Bí kálukú ṣe ń kẹ́dùn yàtọ̀ síra. Ohun tó ṣe pàtàkì ni pé: Tí omijé bá fẹ́ máa dà lójú rẹ, ó lè jẹ́ pé “ìgbà sísunkún” tìrẹ nìyẹn.—Oníwàásù 3:4.