Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé c Ìmọ̀ràn kan náà ni ọmọkùnrin kan máa tẹ̀ lé bí ọmọbìnrin kan bá ń rọ̀ ọ́ pé kó bá òun lò pọ̀.