Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Bí àpẹẹrẹ, “Mi ò ní ní ìbálòpọ̀ títí màá fi ṣe ìgbéyàwó, mo sì gbà pé ohun tó dára jù nìyẹn torí pé . . . ” Rí i dájú pé ohun tó o kọ sílẹ̀ jẹ́ ìwà tíwọ alára gbà pé ó yẹ kéèyàn máa hù, kì í ṣe ìwà táwọn kan ń hù.