Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé d Rúùtù jẹ́ ọ̀kan lára àwọn obìnrin márùn-ún tí Bíbélì to orúkọ wọn sára ìlà ìdílé Jésù. Òmíràn tún ni Ráhábù, tó jẹ́ ìyá Bóásì. (Mát. 1:3, 5, 6, 16) Bíi ti Rúùtù, òun náà kì í ṣe ọmọ Ísírẹ́lì.