Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Bó tilẹ̀ jẹ́ pé Bíbélì sọ pé Jèhófà ti ‘sé ilé ọlẹ̀ Hánà,’ kò sí ẹ̀rí tó fi hàn pé inú Ọlọ́run kò dùn sí obìnrin onírẹ̀lẹ̀ àti olóòótọ́ yìí. (1 Sám. 1:5) Nígbà míì, Bíbélì máa ń sọ pé Ọlọ́run ló ṣe àwọn nǹkan kan tó wulẹ̀ fàyè gbà fún àwọn àkókò kan.