Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Kámẹ́lì yìí kì í ṣe Òkè Ńlá Kámẹ́lì tí gbogbo èèyàn mọ̀ o, èyí tó wà lápá àríwá, níbi tí wòlíì Èlíjà ti ko àwọn wòlíì Báálì lójú lẹ́yìn ìgbà náà. (Wo Orí 10.) Ìlú kan ní ìkángun aginjù tó wà lápá gúúsù ni.