Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Lóòótọ́ àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì rí i pé ó ṣe pàtàkì kéèyàn jáde kúrò nínú àwọn ẹ̀sìn tó jẹ́ ọ̀rẹ́ ayé, ṣùgbọ́n fún ọ̀pọ̀ ọdún, wọ́n ṣì ń ka àwọn kan tí kì í ṣe ara àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì àmọ́ tí wọ́n sọ pé àwọn nígbàgbọ́ nínú ẹbọ ìràpadà àti pé àwọn ya ara wọn sí mímọ́ fún Ọlọ́run, kún ara àwọn arákùnrin wọn nínú Olúwa.